Jobu 42:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sì sí ọmọbinrin tí ó lẹ́wà bí àwọn ọmọbinrin Jobu ní gbogbo ayé. Baba wọn sì fún wọn ní ogún láàrin àwọn arakunrin wọn.

Jobu 42

Jobu 42:6-16