Jobu 31:36-38 BIBELI MIMỌ (BM)

36. Dájúdájú, ǹ bá gbé e lé èjìká mi,ǹ bá fi dé orí bí adé;

37. ǹ bá sọ gbogbo ìgbésẹ̀ mi fún Ọlọrun,ǹ bá bá a sọ̀rọ̀ bí ìjòyè.

38. “Bí ilẹ̀ mi bá kígbe ẹ̀san lé mi lórí,tí àwọn poro oko mi sì ń sọkún;

Jobu 31