Jobu 32:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọkunrin mẹtẹẹta náà kò dá Jobu lóhùn mọ́, nítorí pé ó jẹ́ olódodo lójú ara rẹ̀.

Jobu 32

Jobu 32:1-11