Jobu 30:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn nisinsinyii àwọn tí wọ́n kéré sí mi ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà,àwọn tí baba wọn kò tó fi wé àwọn ajátí ń ṣọ́ agbo ẹran mi.

Jobu 30

Jobu 30:1-7