Jobu 29:24-25 BIBELI MIMỌ (BM)

24. Mo rẹ́rìn-ín sí wọn nígbà tí wọn ń ṣiyèméjì,wọn kò sì lè kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá mi.

25. Mo jókòó bí ọba, mò ń tọ́ wọn sọ́nà,mo dàbí ọba láàrin àwọn ọmọ ogun rẹ̀,bí olùtùnú fún oníròbìnújẹ́.

Jobu 29