Jobu 24:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Kí ló dé tí Olodumare kò fi yan ọjọ́ ìdájọ́,kí àwọn tí wọ́n mọ̀ ọ́n sì rí ọjọ́ náà?

2. “Àwọn eniyan a máa hú òkúta ààlà kúrò,láti gba ilẹ̀ ẹlòmíràn kún tiwọn,wọn a máa fi ipá sọ agbo ẹran ẹlòmíràn di tiwọn.

Jobu 24