Jobu 24:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn eniyan a máa hú òkúta ààlà kúrò,láti gba ilẹ̀ ẹlòmíràn kún tiwọn,wọn a máa fi ipá sọ agbo ẹran ẹlòmíràn di tiwọn.

Jobu 24

Jobu 24:1-9