Jobu 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí mo sọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ kò mú kí ara tù mí,bí mo bá sì dákẹ́, ṣé dídákẹ́ lè tán ìrora mi?

Jobu 16

Jobu 16:3-10