Jobu 16:5-7 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Mo lè fi ọ̀rọ̀ ẹnu mi fun yín lókun,kí ọ̀rọ̀ ìtùnú mi sì mú kí ara tù yín.

6. “Bí mo sọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ kò mú kí ara tù mí,bí mo bá sì dákẹ́, ṣé dídákẹ́ lè tán ìrora mi?

7. Dájúdájú Ọlọrun ti dá mi lágara,ó ti sọ gbogbo ilé mi di ahoro.

Jobu 16