Jobu 11:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkàn rẹ óo balẹ̀, nítorí pé o ní ìrètí,a óo dáàbò bò ọ́, o óo sì sinmi láìséwu.

Jobu 11

Jobu 11:11-20