Jeremaya 7:30 BIBELI MIMỌ (BM)

“Àwọn ọmọ Juda ti ṣe nǹkan burúkú. Wọ́n gbé ère wọn kalẹ̀ ninu ilé tí à ń fi orúkọ mi pè, wọ́n sì ti sọ ọ́ di aláìmọ́.

Jeremaya 7

Jeremaya 7:25-34