Jeremaya 7:29 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gé irun orí yín dànù,ẹ lọ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn lórí òkè,nítorí OLUWA ti kọ ìran yín sílẹ̀,ó ti fi ibinu ta ìran yín nù.

Jeremaya 7

Jeremaya 7:27-34