Jeremaya 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, ẹ lọ sí ilé mi ní Ṣilo, níbi ìjọ́sìn mi àkọ́kọ́, kí ẹ sì wo ohun tí mo ṣe sí i, nítorí ìwà burúkú Israẹli, àwọn eniyan mi.

Jeremaya 7

Jeremaya 7:3-16