Jeremaya 7:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé lójú tiyín, ilé yìí, tí à ń fi orúkọ mi pè, ó ti wá di ibi ìsápamọ́ sí fún àwọn olè? Mo ti ri yín; èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Jeremaya 7

Jeremaya 7:8-13