Jeremaya 6:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Lóòótọ́ à ń fi ẹwìrì fẹ́ iná,òjé sì ń yọ́ lórí iná;ṣugbọn alágbẹ̀dẹ ń yọ́ irin lásán ni,kò mú ìbàjẹ́ ara rẹ̀ kúrò.

Jeremaya 6

Jeremaya 6:27-30