Jeremaya 6:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọ̀tẹ̀, aláìgbọràn ni gbogbo wọn,wọn á máa sọ̀rọ̀ eniyan lẹ́yìn.Wọ́n dàbí idẹ àdàlú mọ́ irin,àmúlùmálà ni gbogbo wọn.

Jeremaya 6

Jeremaya 6:21-30