Jeremaya 6:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ̀yin ọmọ Bẹnjamini, ẹ sá àsálà!Ẹ sá kúrò ní Jerusalẹmu.Ẹ fọn fèrè ogun ní Tekoa,kí ẹ ṣe ìkìlọ̀ fún wọn ní Beti Hakikeremu,nítorí pé nǹkan burúkúati ìparun ńlá ń bọ̀ láti ìhà àríwá.

2. Jerusalẹmu, Ìlú Sioni dára, ó sì lẹ́wà,ṣugbọn n óo pa á run.

Jeremaya 6