Jeremaya 6:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin ọmọ Bẹnjamini, ẹ sá àsálà!Ẹ sá kúrò ní Jerusalẹmu.Ẹ fọn fèrè ogun ní Tekoa,kí ẹ ṣe ìkìlọ̀ fún wọn ní Beti Hakikeremu,nítorí pé nǹkan burúkúati ìparun ńlá ń bọ̀ láti ìhà àríwá.

Jeremaya 6

Jeremaya 6:1-2