Jeremaya 52:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọpọ́n idẹ orí rẹ̀ ga ní igbọnwọ marun-un, wọ́n ṣe ẹ̀wọ̀n bí ẹ̀gbà ọrùn ati èso Pomegiranate yí ọpọ́n náà ká.

Jeremaya 52

Jeremaya 52:17-30