Jeremaya 52:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn òpó náà ga ní igbọnwọ mejidinlogun, àyíká wọn jẹ́ igbọnwọ mejila, wọ́n nípọn, ní ìka mẹrin, wọ́n sì ní ihò ninu.

Jeremaya 52

Jeremaya 52:16-31