Jeremaya 50:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbéraga, o óo fẹsẹ̀ kọ, o óo sì ṣubú,kò ní sí ẹni tí yóo gbé ọ dìde.N óo dá iná kan ninu àwọn ìlú rẹ,iná náà yóo sì jó gbogbo àyíká rẹ.”

Jeremaya 50

Jeremaya 50:24-37