Jeremaya 50:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gbógun ti Babiloni yíká, gbogbo ẹ̀yin tafàtafà. Ẹ máa ta á lọ́fà, ẹ má ṣẹ́ ọfà kankan kù, nítorí pé ó ti ṣẹ OLUWA.

Jeremaya 50

Jeremaya 50:9-23