Jeremaya 5:5 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo lọ sọ́dọ̀ àwọn eniyan pataki pataki,n óo sì bá wọn sọ̀rọ̀;nítorí àwọn mọ ọ̀nà OLUWA,ati òfin Ọlọrun wọn.”Ṣugbọn gbogbo wọn náà ni wọ́n ti fa àjàgà wọn dá,tí wọ́n sì ti kọ àṣẹ ati àkóso OLUWA.

Jeremaya 5

Jeremaya 5:4-9