Jeremaya 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ní mo wí lọ́kàn ara mi pé,“Àwọn aláìní nìkan nìwọ̀nyí,wọn kò gbọ́n;nítorí wọn kò mọ ọ̀nà OLUWA,ati òfin Ọlọrun wọn.

Jeremaya 5

Jeremaya 5:2-7