Jeremaya 49:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, ìwọ Heṣiboni,nítorí pé ìlú Ai ti parun!Ẹ sọkún, ẹ̀yin ọmọbinrin Raba!Ẹ ró aṣọ ọ̀fọ̀,ẹ máa sọkún, kí ẹ sì máa sá sókè sódò láàrin ọgbà!Nítorí pé oriṣa Moleki yóo lọ sí ìgbèkùn,pẹlu àwọn babalóòṣà rẹ̀ ati àwọn ìjòyè ní ibi ìsìn rẹ̀.

Jeremaya 49

Jeremaya 49:1-10