Jeremaya 49:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, wò ó, àkókò ń bọ̀ tí n óo jẹ́ kí ariwo ogun sọ, ní Raba ìlú àwọn ọmọ Amoni;Raba yóo di òkítì àlàpà,a óo sì dáná sun àwọn ìgbèríko rẹ̀;Israẹli yóo wá pada fi ogun kó àwọn tí wọ́n kó o lẹ́rú.

Jeremaya 49

Jeremaya 49:1-12