Jeremaya 49:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí àwọn tí kò yẹ kí wọ́n jìyà bá jìyà, ṣé ìwọ wá lè lọ láìjìyà? O kò ní lọ láìjìyà, dájúdájú ìyà óo jẹ ọ́.

Jeremaya 49

Jeremaya 49:10-17