Jeremaya 49:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Fi àwọn ọmọ rẹ, aláìníbaba sílẹ̀,n óo pa wọ́n mọ́ láàyè,sì jẹ́ kí àwọn opó rẹ gbẹ́kẹ̀lé mi.

Jeremaya 49

Jeremaya 49:6-21