Jeremaya 48:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọn ń sá fún ogun dúró ní ibi ààbò Heṣiboni,wọn kò lágbára mọ́,nítorí iná ṣẹ́ jáde láti Heṣiboniahọ́n iná sì yọ láàrin ilé Sihoni ọba;iná ti jó Moabu tíí ṣe adé àwọn ọmọ onídàrúdàpọ̀ ní àjórun,

Jeremaya 48

Jeremaya 48:44-47