Jeremaya 48:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó ń sálọ nítorí ìpayà,yóo jìn sinu ọ̀gbun,ẹni tí ó bá sì jáde ninu ọ̀gbunyóo kó sinu tàkúté.N óo mú kí àwọn nǹkan wọnyi dé bá Moabunígbà tí àkókò ìjìyà rẹ̀ bá tó.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.

Jeremaya 48

Jeremaya 48:42-47