Jeremaya 45:4 BIBELI MIMỌ (BM)

“Èmi ń wó ohun tí mo kọ́ lulẹ̀, mo sì ń tu ohun tí mo gbìn, bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ gbogbo ilẹ̀ náà rí.

Jeremaya 45

Jeremaya 45:1-5