Jeremaya 45:3 BIBELI MIMỌ (BM)

ò ń sọ pé, o gbé, nítorí pé OLUWA ti fi ìbànújẹ́ kún ìrora rẹ; àárẹ̀ mú ọ nítorí ìkérora rẹ, o kò sì ní ìsinmi.

Jeremaya 45

Jeremaya 45:1-5