Jeremaya 44:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní, ‘Ẹ wò ó, n óo dójúlé yín, n óo sì pa gbogbo ọmọ Juda run.

Jeremaya 44

Jeremaya 44:9-20