Jeremaya 44:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn kò rẹ ara wọn sílẹ̀ títí di òní, tabi kí wọn bẹ̀rù, tabi kí wọ́n pa òfin ati ìlànà tí mo fún ẹ̀yin ati àwọn baba yín mọ́.’

Jeremaya 44

Jeremaya 44:5-13