Jeremaya 44:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkan tí Jeremaya gbọ́ nípa gbogbo àwọn Juu tí wọn ń gbé Migidoli ati Tapanhesi, ati Memfisi ati ilẹ̀ Patirosi ní ilẹ̀ Ijipti nìyí.

Jeremaya 44

Jeremaya 44:1-3