Jeremaya 43:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo fọ́ àwọn òpó ilé oriṣa Heliopolisi tí ó wà ní ilẹ̀ Ijipti, yóo sì dáná sun àwọn ilé àwọn oriṣa ilẹ̀ Ijipti.”

Jeremaya 43

Jeremaya 43:9-13