Jeremaya 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àjálù ń ṣubú lu àjálù,gbogbo ilẹ̀ ti parun.Lójijì àgọ́ mi wó lulẹ̀,aṣọ títa mi sì fàya ní ìṣẹ́jú kan.

Jeremaya 4

Jeremaya 4:12-23