Jeremaya 4:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Oró ò! Oró ò!Mò ń jẹ̀rora!Àyà mi ò!Àyà mi ń lù kìkìkì,n kò sì lè dákẹ́;nítorí mo gbọ́ ìró fèrè ogun, ati ariwo ogun.

Jeremaya 4

Jeremaya 4:10-27