Jeremaya 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ Jerusalẹmu, fọ ibi dànù kúrò lọ́kàn rẹ,kí á lè gbà ọ́ là.Yóo ti pẹ́ tó tí èrò burúkú yóo fi máa wà lọ́kàn rẹ?

Jeremaya 4

Jeremaya 4:6-16