Jeremaya 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wò ó! Ó ń bọ̀ bí ìkùukùu,kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ dàbí ìjì.Àwọn ẹṣin rẹ̀ yára ju àṣá lọ.A gbé, nítorí ìparun dé bá wa.

Jeremaya 4

Jeremaya 4:3-19