Jeremaya 37:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba Sedekaya rán Jehukali, ọmọ Ṣelemaya, ati Sefanaya, alufaa, ọmọ Maaseaya, sí Jeremaya wolii, pé kí ó jọ̀wọ́ bá àwọn gba adura sí OLUWA Ọlọrun.

Jeremaya 37

Jeremaya 37:1-6