Jeremaya 37:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Sedekaya ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ ati àwọn eniyan náà kò pa ọ̀rọ̀ tí OLUWA ní kí Jeremaya wolii sọ fún wọn mọ́.

Jeremaya 37

Jeremaya 37:1-10