Jeremaya 36:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ìjòyè bá sọ fún Baruku pé kí òun ati Jeremaya lọ sápamọ́, kí wọn má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ ibi tí wọ́n wà.

Jeremaya 36

Jeremaya 36:14-25