Jeremaya 36:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Baruku bá dá wọn lóhùn pé, Jeremaya ni ó sọ gbogbo ọ̀rọ̀ náà fún òun ni òun fi kọ ọ́ sinu ìwé.

Jeremaya 36

Jeremaya 36:11-19