Jeremaya 32:40 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo bá wọn dá majẹmu ayérayé, pé n kò ní dẹ́kun ati máa ṣe wọ́n lóore. N óo fi ẹ̀rù mi sí wọn lọ́kàn, kí wọn má baà yapa kúrò lọ́dọ̀ mi mọ́.

Jeremaya 32

Jeremaya 32:36-44