Jeremaya 32:39 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún wọn ní ọkàn ati ẹ̀mí kan, kí wọn lè máa bẹ̀rù mi nígbà gbogbo, kí ó lè dára fún àwọn ati àwọn ọmọ wọn lẹ́yìn wọn.

Jeremaya 32

Jeremaya 32:38-43