Jeremaya 30:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibinu gbígbóná OLUWA kò ní yipada,títí yóo fi mú èrò ọkàn rẹ̀ ṣẹ.Òye nǹkan wọnyi yóo ye yín ní ọjọ́ ìkẹyìn.

Jeremaya 30

Jeremaya 30:18-24