Jeremaya 30:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ wọn yóo rí bí wọn ti rí ní àtijọ́,àwọn ìjọ wọn yóo fi ìdí múlẹ̀ níwájú mi.N óo sì fi ìyà jẹ gbogbo àwọn tí wọn ń ni wọ́n lára.

Jeremaya 30

Jeremaya 30:13-22