Jeremaya 30:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Orin ọpẹ́ yóo máa ti ibẹ̀ jáde wá,a óo sì máa gbọ́ ohùn àwọn tí ń ṣe àríyá pẹlu.N óo bukun wọn, wọn óo di pupọ,n óo sọ wọ́n di ẹni iyì, wọn kò sì ní jẹ́ eniyan yẹpẹrẹ.

Jeremaya 30

Jeremaya 30:13-24