Jeremaya 3:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítòótọ́, ẹ̀tàn ni àwọn òkè,ati gbogbo ohun tí wọn ń lọ ṣe níbẹ̀;dájúdájú lọ́dọ̀ OLUWA Ọlọrun wa ni ìgbàlà Israẹli wà.

Jeremaya 3

Jeremaya 3:14-25